Our Services



News From The BBC

A Yoruba Perspective


Bí ètò ìsìnkú Pope Francis yóò ṣe wáyé àti àwọn èèyàn tí yóò wà níbẹ̀
Eto isinku Pope Francis yoo waye ni Vatican ni owurọ ọjọ Abamẹta.

Alàgbà ni ọkọ mi ní ṣọ́ọ̀ṣì, wòólì ni mí fún ogún ọdún kí ń tó di Yeye Olokun - Omolara Fanimokun
Arabinrin Omolara ṣalaye ninu ifọrọwanilẹnuwo to ṣe pẹlu BBC Yoruba wi pe oun ṣe ẹsin musulumi ri, bakan naa loun tun lo ogun ọdun ni ṣọọṣi gẹgẹ bii wolii ijọ kan ki oun to wa gba ibi iṣẹ ti ori ran oun lọ eyi ti i ṣe bibọ okun.

Iléeṣẹ́ ológun bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ ọ̀tun lóri ẹgbẹ́ agbébọn Mahmuda tó n ṣoro ní Kwara
O sọ eyi lasiko to n ba awọn Ologun sọrọ nigba to ṣe abẹwo si baraka Ologun to wa ni Sobi niluu Ilorin, to jẹ olu ilu ipinlẹ Kwara.

Kí ló fa ìyanṣẹ́lódì àjọ NiMet tó n ṣàkóbá fún ìrìnàjò ọkọ̀ òfurufú ní Naijiria?
Ọpọ arinrin-ajo ni ko ri baalu gbe wọn lọ si ibi ti wọn n lọ nitori awọn oṣiṣẹ ajọ Nimet to da iṣẹ silẹ.

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Àkójọpọ̀ àwọn ìròyìn káàkiri Nàìjíríà tí Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́.

Ẹ fura o! Èèyàn 135,000 ló ní HIV l'Eko nìkan - Wo bí o ṣe lè dáàbò bo ara rẹ
Ajọ NACA ni kaka ko san lara orilẹede Naijiria nipa aarun HIV, nise ni iye awọn to n ko aarun naa ni Naijiria n pọ sii.

Báwo ni àwọn ohun èèlò ìkunjú tí ò ń lò ṣe burú sí?
Báwo ni o ṣe máa ń fọ àwọn búrọ̀ṣì tí ò ń lò láti fi kun ojú? Ṣé o ti yá másíkárà ọ̀rẹ́ ẹ̀ rẹ rí tàbí lo ìtọ́tè wo níbi tí ó ti fẹ́ rà á? Èwo nínú àwọn ohun èèlò ìkunjú rẹ ni àwọn kòkòrò àìfojúrí wà nínú rẹ̀ jùlọ - ṣé másíkárà ni, tìròó, kàìnkàìn tàbí àwọn búrọ́ọ̀ṣì?

Ṣé lóòótọ́ ni pé ilé ejọ̀ ní kí wọ́n fi Simon Ekpa ránṣẹ́ sí Naijiria?
Saaju ni Ijọba apapọ kede pe adari ẹgbẹ IPOB to n ja fun ominira orilẹede Biafra, Simon Ekpa, atawọn mẹrindinlogun mii n ṣatilẹyin owo fawọn agbesunmọmi ni Naijiria.

'A kàn ṣàdédé rí àwọn agbébọn tí wọ́n ṣíná ìbọn bolẹ̀, pa èèyàn mẹ́jọ, inú ìbẹ̀rù là ń gbé báyìí'
Ejire-Adeyemi sọ pé ni nǹkan bíi aago mẹ́sàn-án àbọ̀ alẹ́ ọjọ́ Ajé, ọjọ́ Kọkànlélógún, oṣù Kẹrin, ọdún 2025 láwọn agbébọn náà yawọ ibùdókọ̀ náà tí wọ́n sì ṣíná ìbọn bolẹ̀ sáwọn èèyàn tó ń gbafẹ́ ní ilé ìgbafẹ́ kan tó wà ní ẹ̀gbẹ́ ibùdókọ̀ náà.

Pásítọ̀ kó sí gbaga fún ṣíṣe aṣemáṣe pẹ̀lú ọmọdé tó jẹ́ àkàndá l'Ondo
Iléeṣẹ́ ààbò Amotekun ní àwọn ti bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí ẹ̀sùn náà látàrí bí pásítọ̀ ọ̀hún ṣe jiyàn wí pé òun fún ọmọ náà lóyún.

Báwo ni wọ́n ṣe ń yan Póòpù tuntun?
Ti asiko ba ti to lati yan Poopu tuntun ni wọn maa ke pe gbogbo awọn cardinal lati wa si Vatican, ni Rome.

Darapọ̀ mọ́ wa lórí WhatsApp
Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ

Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa ẹgbẹ́ agbébọn Mahmuda tó ń ṣoro nípìnlẹ̀ Kwara
Bẹẹ ba gbagbe,Ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Kwara ni awọn ti bẹrẹ iwadii lori awọn agbebọn to ṣe ìkọlu si ibudokọ kan ni Ilesha Baruba,

Mọ̀ nípa ọdún eégún ìlú Ekan-Meje, níbi tó ti jẹ́ èèwọ̀ láti gbé àjẹkù oúnjẹ́ lọ sílé látibi ọdún
Ni ilu Ekan meje to wa ni ijọba ibilẹ Ekiti, ipinlẹ Kwara, ọdun eegun ko gbẹyin nibẹ amọ bayii la n ṣe nilẹ wa, o le jẹ eewọ ni ilẹ ibomiran.

Afurasí tó ń ṣagolo-ṣàgò gún ọmọ-ọmọ olórin Asiko, Comfort Omoge pa l'Ondo
''Lopopona Ayeka si Igbokoda ni ede-ai-yede ti bẹ silẹ laarin oloogbe OgoOluwa ati Mohammed to n ṣagolo.''

Ọkọ olùrànlọ́wọ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ Delta dèrò àhámọ́ ọlọ́pàá lórí ẹ̀sùn pé ó ṣekúpa ìyàwó rẹ̀
Agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Delta, SP Bright Edafe, ṣalaye pe gbọ yii sọ yii ori ayelujara lasan ni ọrọ tawọn kan n gbe kiri pe ọkọ Shimite lo pa a nigba ti wọn n ja.

Yàrá tí wọ́n ti ń ṣàkóso ọ̀rọ̀ àwọn ẹlẹ́wọ̀n jóná dèérú nílé ẹjọ́ ní ìpínlẹ̀ Osun, ariwo sọ
JUSUN ni irufẹ ikọlu bayii n gbogun ti agbara ofin ati idajọ ododo nipinlẹ Osun.

Fásitì UI kìlọ̀ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọ́n obìnrin tí ìròyìn sọ pé, wọ́n n ta ẹyin ilé ọmọ wọn
Aderonke Ajayi, oludari ẹka ile ileẹkọ naa ni ọpọ awọn akẹkọọ fasiti ni ọpọ akẹkọọ ti sọ ara wọn di oniṣowo ẹyin ile ọmọ,

Èyí ni ìdí tí mo ṣe fi iṣẹ́ Fada sílẹ̀ nínú ìjọ Àgùda, tí mo sì di oníṣẹ̀ṣe
Ninu ifọrọwanilẹnuwo ti o ṣe pẹlu BBC Igbo, Obiagbaosogu sọ pe ki i ṣe nitori ki oun le lanfaani lati maa ba obinrin ni ibalopọ loun ṣe fi iṣẹ Fada silẹ gẹgẹ bi ọpọ eeyan ṣe ro.

Ṣe ó ṣeéṣe kí wọ́n yan Póòpù tuntun láti Africa?
Ni Afrika, ijọ ọhun pọ si ni ida 3.31% laarin ọdun 2022 si 2023, ti atẹjade lati Vatican si fi han pe pe 20% awọn ọmọ ijọ naa lo n gbe ni Afrika.

Francis, ẹ̀ṣọ́ aláàbò nílé ijó tó di Póòpù tó mú àyípadà ńlá bá ìjọ Kátólíìkì
Oun ni Poopu akọkọ to wa lati ilẹ America tabi Hemisphere. Lati ọdun 741 ti Gregory III lati syria, ti ku, ẹnikẹni ti kii ṣe ọmọ ilẹ yuroopu ko jẹ Poopu.

Ọmọ Ghana mẹ́sàn án tí wọ́n fi iṣẹ́ tàn kúrò nílé, bá ara wọn nígbèkùn ní Mowe, nípìnlẹ̀ Ogun
Atẹjade ti So-Safe fi ṣọwọ si BBC, ṣalaye pe inu ile oniyara mẹta kan to wa lagbegbe Oke Sioni, ni Mowe ni wọn ti awọn ọmọ Ghana naa mọ.

Kìnìún wọ ilé onílé, ó pa ọmọ ọdún mẹ́rìnlá
Àjọ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ àwọn ẹranko aginjù ní Kenya, Kenya Wildlife Service, KWS sọ pé ní ilé ìgbé àwọn ọmọ náà, tí kò jìnà síbi igbó ọba tí kìnìún ọ̀hún wà, ló ti ṣe ìkọlù si.

Pope Francis ti jáde l'áyé
Olori Alufaa ijọ Aguda, Pope Francis, ti jade laye.

Àwọn ajínigbé ṣọṣẹ́ ní Kwara, jí gbogbo èèrò inú ọkọ̀ gbé
Ọkan lara awọn olugbe ilu Obbo Aiyegunle to ba BBC News Yoruba sọrọ, Ọgbẹni Layọde salaye pe awọn ajinigbe naa ko awọn agbalagba to wa ninu ọkọ naa lọ amọ ti wọn fi awọn ọmọde silẹ.

Ṣé lóòótọ́ ni ẹgbẹ́ agbébọn tuntun Mahmuda, kọlu àwọn agbègbè kan ní Kwara?
Adeyemi ni iroyin to ni eeyan mẹdogun padanu ẹmi wọn lo jẹ irọ to jina si otitọ, to si n si awọn araalu lọna.

Ìlú Igboho rèé, níbi tí ọba mẹ́ta ti ń ṣèlú, ta ni ojúlówó ọba láàrin wọn?
BBC Yorùbá dé ìlú Igboho láti wá ìdáhùn sí ọ̀rọ̀ tó ń jà ràìn-ràìn pé Ta ni ojúlówó ọba ìlú Igboho láàrin Alepata, Onigboho ati Ona Onibode.

Obìrin méjì pàdánù ẹ̀mí wọn lábé ilé tó dàwó ni Ojodu-Berger, orí kó mọ́kànlá yọ
Ní agbègbè Oremeta, Ojodu-Berger ni ilé náà dàwó ní nǹkan bíi aago mẹ́jọ òwúrọ̀ gẹ́gẹ́ bí nǹkan táwọn tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣojú wọn ṣe sọ.

Ǹjẹ́ o mọ ìdí tí gbẹ̀rẹ̀bí fi má n jáde sí ara, àti pé ṣé ó ṣeéṣe láti dènà rẹ̀?
Ọ̀pọ̀ ló máa ń ná owó ribiribi láti ri dájú pé gbẹ̀rẹ̀bí ara wọn parẹ́ tàbí láti má ri mọ́ pátápátá.

Gbajúmọ̀ olórin ẹ̀mí, Bolaji Olarewaju jáde láyé
Àtẹ̀jáde kan táwọn ẹbí olóògbé náà fi léde ṣàlàyé pé ọjọ́ Àbámẹ́ta ni akọrin ẹ̀mí náà dágbére fáyé.

Ṣó o láyà? Tope Osoba fakọyọ nínú ìmọ̀ èdè Yoruba
Tope Osoba gbiyanju, o si fi han pe ọmọ Yoruba atata ni ohun.

Local Housing

This is one of the main issues facing local people. The inadequacy of social housing stock continues to be the main concerns of local people. And it is getting worst.

Read More

Drugs And Illegal Substances

Taking illegal drug is always fraught with danger. You don't need me to tell you that - your grand mother will say the same. The high very often tend to perpetual low that you will never get out from. Get advise now before it is too late

Read More

Knife Attacks

Who goes around with a knive as weapon of protection is deluded. It will inevitably be your comeuppance. Just in case you do not understand, it will kill you. There is no justification for carrying a knive excerpt when you are foraging in the jungle.

Read More

Gang Culture

We were all young once - doing things adults will frown upon. This was at school or in the play grounds. But as we grew up, people we wanted to associate with start to shrink in numbers as our brain matured correspondingly and as a result doing the right thing. Pick your friends judiciously.

Read More

Local Parks

From a personal experience - the local park is a refuge for meditation,physical exploration and mental rejuvination. Just go for a slow run and see how you feel afterwards. Physical and mentally rewarding. Don't just take my words for it - it is a scientific fact. Please do try it.

Read More

24/7 Support

We are your one stop local solution advocate. Dont't carry all that weight on your own we are here to not only relief some of it, but to help you get back to you again.

Read More
Established since 2000

We Are Ready To Assist